Business

N I G E R I A

Africa In Miniature

World News in Yoruba


From The BBC

Ìgbésẹ̀ láti pe Natasha Akpoti padà sílé ìgbìmọ̀ aṣòfin kùnà lábẹ́ òfin-INEC
Atẹjade naa ka pe: "Iwe ifisun to n pe fun ipadabọ sẹnetọ to n ṣojuu Aarin Gbungbun Kogi, kuna lati ba abala 69, ofin orilẹ ede Naijiria ti wọn ṣe ni 1999 mu."


Trump kéde owó orí tuntun, Naijiria, South Afrika, China àti EU fara gbá a
Kenya, Ghana, Ethiopia, Tanzania, Uganda, Senegal ati Liberia wa lara awọn orilẹede ti owo ori ti wọn yoo maa san ko ni kọja 10% lọ.


Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Àkójọpọ̀ ìròyìn káàkiri Nàìjíríà tí kò ṣe é má gbọ̀ ọ́


Àwọn olè jí mi gbé, gba gbogbo owó tó wà ní àkáǹtì mi nílé ìtura nígbà tí mo wà lóko eré - Regina Chukwu
Nínú fídíò kan tó fi sórí YouTube, òṣèré náà ní àwọn olè yawọ ilé ìtura tí àwọn wà tí wọ́n sì jí òun gbé.


Ṣé lóòótọ́ ni CBN fẹ́ tẹ owó bébà ₦5,000 ati ₦10,000 tuntun jáde?
Iroyin kan ni igbakeji gomina banki naa, Ọmọwe Ibrahim Tahir , lo wa nidi titẹ owo tuntun ọhun.


Ìgbòkè-gbodò ọkọ̀ àti èrò fọ́jú pọ̀ lánàá bí Ìjọba Eko ṣe ti afárá Indepence pa, aráàlú ń ké ìrora
Lati owurọ kutu Ọjọruu naa ni wahala ọhun ti bẹrẹ, awọn ọkọ akero ati aladaani ko rọna gba kọja nitori afara to so Mekwen, Marina, CMS pọ ti wọn ni wọn n tunṣe.


Àlàyé rèé lórí bí mo ṣe móríbọ́ níbi ìṣẹ̀lẹ̀ ìpànìyàn ní ìlú Uromi
BBC bá ẹbí àwọn tó pàdánù ẹ̀mí wọn nínú ìkọlù náà àti ẹnìkan tó móríbọ́ sọ̀rọ̀.


Ǹjẹ́ ó tọ́ fún àgbàlagbà láti máa mu omi ọyàn èyí tí ọ̀pọ̀ ń pè ní wúrà inú ìgò?
Imọ ijinlẹ sayẹnsi ti fi han pe omi ọmu ṣe pataki fun idagbasoke awọn ọmọde amọ awọn agbalagba kan ti n mu u bayii latari anfani inu rẹ.


Ọmọbìnrin tó ń gbálẹ̀ pẹ̀lú ìyá rẹ̀ lójú pópó l'Eko rí ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ gbà lọ́wọ́ aláàánú dé fásitì
Nígbà to n sọ iriri ti ara rẹ gan an, Tunde Onakoya ni iya mi naa maa n gbalẹ kaakiri tẹlẹ, koda, iya mi máa n ko gọta lọdun 2016.


Ilé-ẹjọ́ fagile ẹjọ̀ tó tako ìjáwé-olúborí Gómìnà Okpebholo l'Edo
Nibi igbẹjọ akọkọ to waye l’Ọjọruu, ọjọ keji, oṣu kẹrin ọdun 2025, ni kootu ti da ẹjọ ti ẹgbẹ oṣelu Action Alliance (AA) pe tako Okpebholo, nu.


Ọ̀rọ̀ ajé Nàìjíríà kò bá ti gbòòrò tó bá jẹ́ pé ẹ̀mi ni ààrẹ, mo le è ṣe àkóso dára ju Tinubu lọ - Peter Obi, ẹnu dùn ròfọ́ -iléeṣẹ́ ààrẹ fèsì
Peter Obi ní kò yẹ kí Tinubu gbé ìgbésẹ̀ tó gbé lórí owó Náírà nígbà tí Nàìjíríà kò tíì máa pèsè àwọn ọjà tó bó ṣe yẹ.


Láì náání ìkéde kóníléógbélé, tìlù-tìfọn láwọn aráàlú Natasha Akpoti fi kí i káàbọ̀, ó ní ilé baba ọmọ, kìí ba ọmọ lẹ́rùn
Ijọba ipinlẹ Kogi paṣẹ pe ẹnikẹni ko gbọdọ korajọ, o tun kede konileogbele ni wakati diẹ si asiko ti Natasha yoo wọ ilu.


Kókó mẹ́fà nípa Bashir Ojulari ti Tinubu yan bíi adarí ìgbìmọ̀ alákòsóo tuntun fún àjọ NNPC
Ileeṣẹ Aarẹ kede awọn adari tuntun fun ajọ NNPC, ti Bashir Ojulari si jẹ adari nigba ti Ahmadu Kida jẹ alaga.


Darapọ̀ mọ́ wa lórí WhatsApp
Má jẹ́ kí etí rẹ ó di sí gbogbo ìròyìn ohun tó ń lọ ní Naijiria àti káàkiri àgbáyé. Mọ̀ nípa wọn lórí ìkànnì Whatsapp rẹ


"Tí mi ò bá rí ògùn rà fún ọmọ mi, á máa gé ara rẹ̀ jẹ títí ẹ̀jẹ̀ yóò fi máa ṣàn"
Ọjọ keji osu kẹrin ọdọọdun ni awujọ agbaye ya sọtọ gẹgẹ bii ọjọ pipe akiyesi ara ẹni si arun aidape ọpọlọ ti wọn n pe ni Autism.


Ilé ẹjọ́ ju àlùfáà ìjọ tó fipá bá obìnrin lò pọ̀ sí ẹ̀wọ̀n gbére
Singh, ẹni tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ń tẹ̀lé, di ìlúmọ̀ọ́ká fáwọn iṣẹ́ ìyanu tó máa ń ṣe lórí àwọn aláìsàn nípa gbígbé ọwọ́ lé èèyàn lórí tí onítọ̀hún yóò sì gbádùn.


Ariwo sọ bí ọ́kùnrin kan ṣe kéde pé òun ti ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú ọmọdébìnrin ọdún mẹ́jọ tí wọ́n ń wá
Fadumo Ahmed to jẹ adari ajọ to n ja fẹtọ awọn obinrin ni Somalia sọ fun BBC pe ohun to buru ju nipa iṣẹlẹ naa ni pe ọpọ lo ti ro pe awọn ajinigbe lo gbe ọmọ naa.


Òṣèré tíátà, Biola Adebayo ra ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ fún Dupe Jaiyesinmi, fẹ́ gba ọmọ tọ́ fún-un lábẹ̀ ìjọba Oyo
Jaiyesimi sọ pe ọmọ awọn mọlẹbi atawọn ọmọ ọlọmọ mii loun gba tọ, awọn eeyan na a ko ranti oun lọjọ ogbo, o si jẹ ibanujẹ fun oun.


Ṣé Donald Trump le ṣe ààrẹ Amẹ́ríkà fún sáà Kẹta?
Donald Trump ní ọ̀pọ̀ èèyàn ń fẹ́ kí òun ṣe sáà kẹta, táwọn alátìlẹyìn rẹ̀ sì ń sọ pé ọ̀nà wà láti gbé e gbà.


Wo àwọn ànfàní tí wíwà nínú oòrùn ń ṣe fún àgọ́ ara
Jijoko sinu oorun lati ma gba oorun naa sara le ṣe agọ ara loore pupọ.


Ọ̀rọ̀ bẹ́yìn yọ lórí ìwọ́de láti yọ ààrẹ ilẹ̀ Zimbabwe torí pé ìlú le
Ọpọ ọmọ ilẹ Zimbabwe joko sile dipo ki wọn bọ soju popo lati se iwọde tori bi awọn agbofinro, ti oju wọn ko rẹrin, se lu igboro pa.


Àlàyé rèé lórí bí mo ṣe móríbọ́ níbi ìṣẹ̀lẹ̀ ìpànìyàn ní ìlú Uromi
BBC bá ẹbí àwọn tó pàdánù ẹ̀mí wọn nínú ìkọlù náà àti ẹnìkan tó móríbọ́ sọ̀rọ̀.


Kí ló kàn lẹ́yìn Ààwẹ̀ Ramadan, ààwẹ̀ Shawwal mẹ́fà ni àbí sísan ààwẹ̀ tí o dín padà?
Ero awọn aafaa ṣọtọọtọ lori eyi to yẹ ko ṣaaju ninu gbigba aawẹ Ramadan ti a din pada tabi gbigba aawẹ Shawwal to jẹ mẹfa.


Bí ọjọ́ ẹ̀tàn, April Fool's Day' se bẹ̀rẹ̀ rèé
Ọjọ́ Kíní, Oṣù Kẹ́rin, ọdọọdún ni àyájọ́ Ọjọ́ 'April Fool' tí àwọn ènìyàn tí máa ń tan àwọn ẹlòmíràn jẹ.


Ladoja lahùn lórí ìkéde ìlú ò fararọ ní Rivers tí ààrẹ Tinubu kéde, gba Wike àti Fubara ní ìmọ̀ràn
Sẹnẹtọ Rashidi Ladoja lasiko to n bawọn akọroyin sọrọ nile rẹ niluu Ibadan sọ ero rẹ nipa ikede ilu o fararọ ni Rivers ti aarẹ Tinubu kede rẹ.


Ọrọ̀-ajé ti fẹsẹ̀ múlẹ̀ l‘Oyo, N12bn la fi ń sanwó oṣù òṣìṣẹ́ ìjọba ìpínlẹ̀, N10bn fún òṣìṣẹ́ ìbílẹ̀ lóṣooṣù - Makinde
Gomina Seyi Makinde ni idagbasoke ati ọrọ aje ipinlẹ Oyo to fẹsẹ mulẹ ko ṣẹyin ibagbepọ alaafia pẹlu iṣọkan to wa laarin awọn araalu.


Ohun méje tó mú ilẹ̀ ríri ní Myanmar fa ikú rẹpẹtẹ tó lé ní 1,700
Awọn aworan to n jade n ṣafihan bi ọpọ ile ṣe ti bajẹ pẹlu awọn ọna, ni olu ilu Thai, Bangkok ni ile alaja ọgbọn (30-storey) ti wọn n kọ lọwọ ti wo lulẹ.


BBC tú àṣírí gbájúẹ̀ tó ń gba owó lọ́wọ́ ọmọ Nàíjíría fún ìpèsè iṣẹ́ ní UK
Lára àwọn èèyàn tó ń lu jìbìtì náà ni dókítà ọmọ Nàìjíríà kan tó ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àjọ ìlera ilẹ̀ UK, NHS ní ẹ̀ka àwọn tó máa ń rí sí ìtọ́jú ààrùn ọpọlọ.


Ọ̀pọ̀ olólùfẹ́ Peller já kúrò lójú òpó TikTok rẹ̀, àwọn kan tún ń dúnkokò láti yìnbọn mọ́ torí ọ̀rọ̀ tó sọ
Peller lórí TikTok tó ṣe sọ pé èèyàn kan dúnkokò mọ́ òun pé wọ́n máa yìnbọn mọ́ òun tí òun bá fi lè kọjá ní agbègbè Lekki Phase 1.


Mó ní òṣìṣẹ́ 42 àmọ́ mò jẹ wọ́n lówó oṣù mẹrin, mò ń la nǹkan kọjá torí ìlú le - Ibrahim Chatta
Ilumọọka oṣere naa ni bi ọrọ-aje Naijiria ṣe dẹnu kọlẹ naa lo fa a toun ko fi ri owo oṣu awọn oṣiṣẹ oun san.


Wọ́n gún ẹ̀ṣọ́ Emir Sanusi ní ọ̀bẹ pa, òmíràn fara gbọgbẹ́ lásìkò tó ń bọ̀ níbi ìrun ọdún Ìtúnu Ààwẹ̀
Agbẹnusọ fun ileesẹ ọlọpaa ni Kano, Abdullahi Kiyawa, lo sisọ loju isẹlẹ naa lọjọ Aiku nilu Kano.


Díẹ̀ ló kù kí n jáwọ́ nínú dídu ipò ààrẹ lásìkò ọ̀wọ́ńgógó Naira, ìṣẹ̀lẹ̀ náà kò kọjú re sí mi – Tinubu
Aarẹ Tinubu sọrọ yii lọjọ Abamẹta, lasiko ti awọn eeyan n ṣinu aawẹ ọjọ naa pẹlu rẹ nile agbara to wa l'Abuja.


Mọ̀ nípa àbá òfin tó lè mú ọ ṣ'ẹ̀wọ̀n tàbí san fáìní N100,000 tí o bá kọ̀ látì dìbò
SERAP sọ ninu iwe to kọ si ile aṣofin pe riran awọn ọmọ Naijiria ti wọn ti to ibo di ṣugbọn ti wọn ko dibo lọ sẹwọn, tako alakalẹ to wa ninu iwe ofin Naijiria àti ẹtọ ọmọniyan lagbaaye.


"Ilé tó lé ní igba ni wọ́n jó ní Erin-Osun, ìgbà kejì tí wọn yóò jó ilé mi rèé, n kò ní aṣọ kankan lọ́rùn mọ́"
BBC Yorùbá dé ìlú Ilobu àti Erin Ile níbi tí ọ̀pọ̀ ẹ̀mí àti dúkìá olówó iyebíye ti ṣòfò, ọ̀pọ̀ èèyàn sí ló fi omijé sọ̀rọ̀ nípa àjálù tó bá wọn."


Kókó ọ̀rọ̀ tí Alaafin Oyo tuntun sọ l'ọdun Ìtúnu Àwé lẹ́yìn tó dé Adé Sango tán ní Koso
Alaafin Owoade to gba ade Sango ni Koso lọjọ Abamẹta ọjọ kọkandinlọgbọn oṣu Kẹta niluu Oyo sọrọ yii ninu ọrọ ikini ku ọdun to fi ranṣẹ sawọn musulumi to n ṣe ọdun itunu awẹ.


Abẹ̀sẹ́kùbíòjò ọmọ Nàìjíríà Olanrewaju ṣubú lulẹ̀ lásìkò tó ń jà lọ́wọ́, ó sì jáde láyé
Fidio ija Olanrewaju ati Mbanugu ti a ri lori itakun ayelujara fi idi rẹ mulẹ wi pe oun gan an lo n lewaju pẹlu ami ayo to pọju ninu ija ọhun ki o to ṣubu lulẹ.


Ìjíròrò láti dáwọ́ oogun dúró láàárín Israel àti Hamas tún gbérasọ
Ìgbésẹ̀ ọ̀tun yìí yóò pèsè fún Hamas láti tú àwọn èèyàn Israel márùn-ún tó wà ní àhámọ́ wọn sílẹ̀, tí wọ́n sì máa sinmi oogun fún àádọ́ta ọjọ́.


One Step At A Time

This old adage, more relevant than ever



Our Objective

  • Support and encourage current members as and when the need arises fairly and honestly
  • Grow our membership by reaching out through formal and informal social gatherings
  • Extend charitable assistance to the needy and wanting
  • Promote and maintain friendship, members and other colleagues who are non members of Soyuznikis-UK
  • Promote the group locally and worldwide
Our Mission
Soyuznikis-UK is a union for Nigerians who have studied in the former Union of Soviets Socialist Republic (USSR). Soyuznikis comes from the Russian word ‘Soyuz’ meaning union. The association was founded in the summer of 2007 during the wedding ceremony of a colleague in London, the idea came about to form an umbrella organisation to bring together and embrace in friendship as it existed amongst us during our stay in the USSR was agreed.

Soyuznikis-UK is a secular and non political organisation. Membership to the group is not dependent on creed, origin, gender or sexuality. We endeavour to be a progressive organisation that will make meaningful contributions to the communities that gave us the opportunity to learn – USSR, the one that now host us - United Kingdom and most especially our nation – Nigeria. The deeds and acts of Soyuznikis-UK are guided by its constitution.

Our general meetings are held on the last Saturday of every month excluding December, when we normally hold our End of Year Party. Ideally, we as a group encourage our friends and familities to join us on our social events as a way of fostering our interpersonal relationships.

Unity Is Strength

Since inception, the association has been lead by the following persons as President. They have made efforts to foster growth and unity among members.

They are:
  1. Mr. Paul Eboh 2007 to 2009
  2. Dr. Ralph Eke 2009 to 2011
  3. Pastor Chioma Ejiofor 2011 to 2012
  4. Mr. Ebenezer Hundeyin 2012 to 2019
  5. Mr. Olushina Alaka 2019 to date


Cancel Culture - Very Divisive

The most dangerous of all falsehoods is a slightly distorted truth. The danger of instant judgements and monolithic narratives are all too prevalent in these deliberations. Where you will find cold-blooded grasping; massive sense of entitlement; an inability to show gratitude; an unrealistic expectation of puritanism from others; and a passionate performance of virtue that is well executed in the public space ( social media) but not in the intimate space of co-habitation and friendship.

These are very trying times. Technology as recent as couple of years ago was supposed to bring us all closer - remember the global village?. The emergence of an old doctrine - critical race theory the epitome of this dramatic change in attitude towards anyone with a different point of view has put paid to that paradigm. These contrive and concerted attack on one race as being the source of the biblical original sin is trivial and false period.

We insulate ourselves in ideological bubbles of similar-thinking people and refuse to countenance or even engage with the truth. We now seems to be building echo chambers with titanium and carbon fibre cladding just to make sure we do not see or hear anything different. If these cancel culture mentality is being adopted to the pandemic, may be herd immunity would have been achieved by now. We have become communities in a dislocated social fabric that is fracturing at an astonishing rate. If we do not amend this fast, rapture seems to be the only ramification.